Lefitiku 7:38 BIBELI MIMỌ (BM)

tí OLUWA paláṣẹ fún Mose, ní orí òkè Sinai ní ọjọ́ tí ó pàṣẹ fún àwọn eniyan Israẹli láti mú ẹbọ wọn wá fún òun OLUWA ninu aṣálẹ̀ Sinai.

Lefitiku 7

Lefitiku 7:32-38