Lefitiku 7:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyíkéyìí ninu àwọn ọmọ Aaroni tí ó bá fi ẹ̀jẹ̀ ati ọ̀rá ẹran náà rúbọ ni ó ni itan ọ̀tún ẹran náà gẹ́gẹ́ bí ìpín tirẹ̀.

Lefitiku 7

Lefitiku 7:26-35