Lefitiku 7:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ lè lo ọ̀rá ẹran tí ó kú fúnra rẹ̀ ati ọ̀rá èyí tí ẹranko burúkú pa, fún ohun mìíràn, ṣugbọn ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹ́.

Lefitiku 7

Lefitiku 7:19-33