Lefitiku 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èyí ni òfin tí ó jẹmọ́ ẹbọ ohun jíjẹ. Àwọn ọmọ Aaroni ni yóo máa rúbọ náà níwájú pẹpẹ, níwájú OLUWA.

Lefitiku 6

Lefitiku 6:4-18