Lefitiku 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo yọ́ gbogbo ọ̀rá akọ mààlúù tí ó fi rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ kúrò, ati gbogbo ọ̀rá tí ó bo nǹkan inú rẹ̀;

Lefitiku 4

Lefitiku 4:2-15