Lefitiku 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti ìka rẹ̀ bọ inú ẹ̀jẹ̀ náà, yóo sì wọ́n ọn sílẹ̀ nígbà meje níwájú OLUWA, níwájú aṣọ ìkélé tí ó wà ní ibi mímọ́.

Lefitiku 4

Lefitiku 4:1-15