Lefitiku 4:23 BIBELI MIMỌ (BM)

nígbà tí wọ́n bá fi ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá yìí hàn án, yóo mú òbúkọ kan tí kò ní àbààwọ́n wá, yóo fi rúbọ.

Lefitiku 4

Lefitiku 4:16-29