Lefitiku 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo sì ti ìka bọ inú ẹ̀jẹ̀ náà, yóo wọ́n ọn sílẹ̀ nígbà meje níwájú OLUWA, níwájú aṣọ ìbòjú tí ó wà níbi mímọ́.

Lefitiku 4

Lefitiku 4:10-22