Lefitiku 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Aaroni yóo sun wọ́n lórí igi tí ó wà ninu iná lórí pẹpẹ; ẹbọ sísun ni, tí ó ní òórùn dídùn, tí inú OLUWA sì dùn sí.

Lefitiku 3

Lefitiku 3:1-8