Lefitiku 27:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ẹnìkan bá ya ilé rẹ̀ sọ́tọ̀ fún OLUWA, alufaa yóo wò ó bóyá ó dára tabi kò dára; iyekíye tí alufaa bá pè é ni iye rẹ̀.

Lefitiku 27

Lefitiku 27:6-17