Lefitiku 26:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi ojurere wò yín, n óo mú kí ẹ máa bímọlémọ, kí ẹ sì pọ̀ sí i, n óo sì fi ìdí majẹmu mi múlẹ̀ pẹlu yín.

Lefitiku 26

Lefitiku 26:1-17