Lefitiku 26:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni ìlànà ati òfin tí OLUWA fi lélẹ̀ láàrin òun ati àwọn ọmọ Israẹli, láti ọwọ́ Mose.

Lefitiku 26

Lefitiku 26:37-46