Lefitiku 26:33 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fọ́n yín káàkiri ààrin àwọn orílẹ̀-èdè, idà ni wọn yóo máa fi pa yín ní ìpakúpa, ilẹ̀ yín ati àwọn ìlú yín yóo di ahoro.

Lefitiku 26

Lefitiku 26:31-36