Lefitiku 26:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹlu gbogbo agbára tí ẹ ní, n óo tẹ̀ yín lórí ba; òjò yóo kọ̀, kò ní rọ̀, ilẹ̀ yóo sì le bí àpáta.

Lefitiku 26

Lefitiku 26:12-21