Lefitiku 26:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo kẹ̀yìn sí yín, àwọn ọ̀tá yín yóo sì ṣẹgun yín. Àwọn tí ẹ kórìíra ni yóo máa jọba lórí yín, ẹ óo sì máa sá nígbà tí ẹnikẹ́ni kò le yín.

Lefitiku 26

Lefitiku 26:11-24