Lefitiku 25:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, iranṣẹ mi ni àwọn ọmọ Israẹli jẹ́, iranṣẹ mi tí mo kó jáde láti ilẹ̀ Ijipti ni wọ́n. Èmi ni OLUWA Ọlọrun rẹ.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:49-55