Lefitiku 25:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sì lè rà láàrin àwọn àlejò tí wọ́n wà láàrin yín ati àwọn ìdílé wọn tí wọ́n wà pẹlu yín, tí wọ́n bí ní ilẹ̀ yín, wọ́n lè di tiyín.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:36-48