Lefitiku 25:39 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí arakunrin rẹ, tí ń gbé tòsí rẹ bá di aláìní, tí ó sì ta ara rẹ̀ fún ọ, o kò gbọdọ̀ mú un sìn bí ẹrú.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:33-43