Lefitiku 25:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ninu gbogbo ilẹ̀ tí ó wà ní ìkáwọ́ yín, ẹ gbọdọ̀ fi ààyè sílẹ̀ fún ẹni tí ó bá fẹ́ ra ilẹ̀ pada.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:15-26