Lefitiku 25:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, nígbà tí ẹ bá ta ilẹ̀ fún aládùúgbò yín, tabi tí ẹ bá ń ra ilẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀, ẹ kò gbọdọ̀ ṣe àìdára sí ara yín.

Lefitiku 25

Lefitiku 25:7-23