Lefitiku 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo ọjọ́ ìsinmi, Aaroni yóo máa tò wọ́n kalẹ̀ níwájú OLUWA nígbà gbogbo, ní orúkọ àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bíi majẹmu títí lae.

Lefitiku 24

Lefitiku 24:1-18