Lefitiku 24:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sì máa tò wọ́n kalẹ̀ sí ọ̀nà meji; mẹfa mẹfa ní ọ̀nà kọ̀ọ̀kan, lórí tabili tí wọ́n fi ojúlówó wúrà ṣe.

Lefitiku 24

Lefitiku 24:1-12