Lefitiku 23:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú àgọ́ ni ẹ óo máa gbé fún gbogbo ọjọ́ meje náà; gbogbo ẹni tí ó bá jẹ́ ọmọ Israẹli ni ó gbọdọ̀ gbé inú àgọ́,

Lefitiku 23

Lefitiku 23:33-44