Lefitiku 23:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ ṣiṣẹ́ rárá, ìlànà ni ó jẹ́ títí lae fún ìrandíran yín, ní gbogbo ibùgbé yín.

Lefitiku 23

Lefitiku 23:21-41