Lefitiku 23:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí kò bá gbààwẹ̀ ní ọjọ́ náà, a óo yọ ọ́ kúrò lára àwọn eniyan rẹ̀.

Lefitiku 23

Lefitiku 23:19-33