Lefitiku 23:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọjọ́ kẹwaa oṣù keje ni ọjọ́ ètùtù. Ẹ ní ìpéjọpọ̀ mímọ́ ní ọjọ́ náà, kí ẹ gbààwẹ̀, kí ẹ sì rú ẹbọ sísun sí OLUWA.

Lefitiku 23

Lefitiku 23:21-36