Lefitiku 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

pé kí ó sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Àwọn àjọ̀dún tí èmi OLUWA yàn tí ó gbọdọ̀ kéde gẹ́gẹ́ bí ìpéjọ mímọ́ nìwọ̀nyí:

Lefitiku 23

Lefitiku 23:1-9