Lefitiku 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo fi òbúkọ kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, ẹ óo sì fi àgbò meji ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan rú ẹbọ alaafia.

Lefitiku 23

Lefitiku 23:18-29