Lefitiku 23:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo ka aadọta ọjọ́ títí dé ọjọ́ keji ọjọ́ ìsinmi keje, lẹ́yìn náà, ẹ óo mú ẹbọ ohun jíjẹ tí ẹ fi ọkà titun ṣe wá fún OLUWA.

Lefitiku 23

Lefitiku 23:6-21