Lefitiku 23:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ tí ẹ bá ń fi ìtí ọkà yín rú ẹbọ fífì, kí ẹ fi ọ̀dọ́ akọ aguntan ọlọ́dún kan, tí kò ní àbààwọ́n rú ẹbọ sísun sí OLUWA.

Lefitiku 23

Lefitiku 23:11-13