Lefitiku 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí oòrùn bá wọ̀, yóo di mímọ́, lẹ́yìn náà, ó lè jẹ ninu àwọn ohun mímọ́ náà nítorí oúnjẹ rẹ̀ ni wọ́n jẹ́.

Lefitiku 22

Lefitiku 22:1-15