Lefitiku 22:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ ba orúkọ mímọ́ mi jẹ́, ẹ gbọdọ̀ máa bọ̀wọ̀ fún mi láàrin gbogbo eniyan Israẹli. Èmi ni OLUWA tí mo sọ yín di mímọ́,

Lefitiku 22

Lefitiku 22:26-33