Lefitiku 22:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa kò gbọdọ̀ sọ àwọn ohun mímọ́ àwọn eniyan Israẹli tí wọ́n fi ń rúbọ sí OLUWA di aláìmọ́.

Lefitiku 22

Lefitiku 22:10-21