Lefitiku 22:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àjèjì kankan kò gbọdọ̀ jẹ ninu àwọn ohun mímọ́, bẹ́ẹ̀ ni àlejò tabi alágbàṣe tí ń gbé ilé alufaa kò gbọdọ̀ jẹ ninu wọn.

Lefitiku 22

Lefitiku 22:1-17