Lefitiku 21:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose sì sọ gbogbo nǹkan tí OLUWA rán an fún Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀, ati fún gbogbo àwọn eniyan Israẹli.

Lefitiku 21

Lefitiku 21:14-24