Lefitiku 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó má baà sọ àwọn ọmọ rẹ̀ di aláìmọ́ láàrin àwọn eniyan rẹ̀; nítorí pé èmi ni OLUWA, tí mo sọ ọ́ di mímọ́.”

Lefitiku 21

Lefitiku 21:10-21