Lefitiku 21:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò gbọdọ̀ lọ sí ibi tí wọ́n bá tẹ́ òkú sí, tabi kí ó sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́, kì báà jẹ́ òkú baba rẹ̀ tabi ti ìyá rẹ̀.

Lefitiku 21

Lefitiku 21:4-13