Lefitiku 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn eniyan tí wọn ń gbé ilẹ̀ náà bá mójú fo ẹni tí ó bá fi ọmọ rẹ̀ fún oriṣa Moleki, tí wọn kò pa á,

Lefitiku 20

Lefitiku 20:1-10