Lefitiku 20:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti jẹ́ mímọ́ fún mi, nítorí pé, mímọ́ ni èmi OLUWA, mo sì ti yà yín sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn eniyan kí ẹ lè máa jẹ́ tèmi.

Lefitiku 20

Lefitiku 20:23-27