Lefitiku 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹbọ rẹ bá jẹ́ ti ohun jíjẹ tí a sè ninu ìkòkò, ìyẹ̀fun rẹ̀ gbọdọ̀ kúnná dáradára kí ó sì ní òróró.

Lefitiku 2

Lefitiku 2:5-11