Lefitiku 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ó ṣẹ́kù ninu ìyẹ̀fun náà di ti Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀. Òun ló mọ́ jùlọ, nítorí pé apá kan ninu ẹbọ sísun sí OLUWA ni.

Lefitiku 2

Lefitiku 2:1-4