Lefitiku 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

O lè mú wọn wá fún OLUWA gẹ́gẹ́ bí ọrẹ àkọ́so oko, ṣugbọn wọn kò gbọdọ̀ fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ bí ẹbọ olóòórùn dídùn.

Lefitiku 2

Lefitiku 2:6-15