Lefitiku 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ó bá ṣẹ́kù ninu ohun jíjẹ náà di ti Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀. Òun ni ó mọ́ jùlọ lára ẹbọ tí a fi iná sun sí OLUWA.

Lefitiku 2

Lefitiku 2:5-15