Lefitiku 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ mú ọkà wá siwaju OLUWA láti fi rúbọ, ó gbọdọ̀ jẹ́ ìyẹ̀fun dáradára, kí ó da òróró ati turari sórí rẹ̀.

Lefitiku 2

Lefitiku 2:1-4