Lefitiku 19:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní ọdún karun-un, ẹ lè jẹ èso wọn, kí wọ́n lè máa so sí i lọpọlọpọ. Èmi ni OLUWA.

Lefitiku 19

Lefitiku 19:23-34