Lefitiku 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ gbọdọ̀ máa tẹ̀lé ìlànà mi kí ẹ sì máa pa àwọn òfin mi mọ́. Ẹni tí ó bá ń pa wọ́n mọ́ yóo wà láàyè. Èmi ni OLUWA.

Lefitiku 18

Lefitiku 18:1-13