Lefitiku 18:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé gbogbo àwọn ohun ìríra wọnyi ni àwọn tí wọ́n ti gbé ilẹ̀ náà ṣáájú yín ti ṣe, tí wọ́n sì fi ba ilẹ̀ náà jẹ́.

Lefitiku 18

Lefitiku 18:26-30