Lefitiku 18:16 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ bá aya arakunrin rẹ lòpọ̀, nítorí pé, ohun ìtìjú ni, ìhòòhò arakunrin rẹ ni.

Lefitiku 18

Lefitiku 18:9-21