Lefitiku 18:14 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ bá aya arakunrin baba rẹ lòpọ̀, nítorí pé, ẹ̀gbọ́n ni ó jẹ́ fún ọ.

Lefitiku 18

Lefitiku 18:12-18