Lefitiku 16:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ ìsinmi tí ó lọ́wọ̀ ni ó jẹ́ fun yín, ẹ sì gbọdọ̀ gbààwẹ̀; ìlànà ni èyí jẹ́ fun yín títí lae.

Lefitiku 16

Lefitiku 16:25-34